YORUBA LANGUAGE FIRST TERM EXAMINATION QUESTIONS FOR SSS 2
YORUBA LANGUAGE FIRST TERM EXAMINATION QUESTIONS FOR SSS 2
FIRST TERM EXAMINATION 2021
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
CLASS: S.S.S.2
1. Igba melo ni Musulumi maa n gbadura loojo? (a) igba mewaa (b) igba marun-un (d) igba meji
2. Awon wo ni o mu esin Musulumi wo ile adulawo? (a) awon ajinhinrere (b) awon Larubawa (d) awon atohunrinwa
3. Awon Musulumi maa n se odun itunu awe lehin awe ojo melo? (a) ogoji ojo (b) ogbon ojo (d) ojo mewaa
4. Ilu wo ni a ti gbe esin Musulumi kale? (a) Ilu Larubawa (b) Ilu Meka (d) Ilu Asia
5. Ojo aiku je ojo isin Pataki fun awon _____ (a) elesin isembaye (b) elesin Musulumi (d) elesin Onigbagbo
6. Odun ajoyo Pataki fun awon elesin Kristieni ni _____ (a) odun igbagbo (b) odun ominira (d) odun Keresimesi
7.Lara esin miran to n tiraka lati gbile ni ile adulawo ni _____ (a) esin Hindu (b) esin oba (d) esin omo iya
8. Ere idaraya ti o je ti awon omode ni _____ (a) ere ita gbangba (b) ere ode oni (d) ere osupa
9. Apeere ere abele ni _____ (a) alo pipa (b) ijakadi (d) ere ipa
10. Oruko miran fun ijakadi ni _____ (a) ere owo (b) eke (d) ese kiku
11. Ere ita gbangba maa n ko omode ni iforiti (a) Beeni (b) Beeko
12. Ewo ni kii se ere ode oni? (a) ere sisa (b) ere ipa (d) Ludo tita
13. Akojopo isori oro ti o fun wa ni itumo ni _____ (a) eyo oro (b) gbolohun (d) oro ise
14. Dide! Je apeere gbolohun _____ (a) gbolohun onibo (b) gbolohun ase (d) gbolohun abode
15. Mo fe ra oko ayokele kan bi oluwa ba pese owo re je apeere gbolohun _____ (a) gbolohun onibo (b gbolohun aba (d) gbolohun abode
16. Gbolohun ti o ni ju awe gbolohun kan lo ti o si le da duro funra re ni _____ (a) gbolohun ase (b) gbolohun alakanpo (d) gbolohun abode
17. Ara ise baale ni _____ (a) yiyanju aawo (b) gbigba iyawo wole (d) ina dida
18. Kini oruko oye oba ilu Osogbo (a) Olubadan (b) Ataoja (d) Olomu
19. Ipinle wo ni Ijebujesa wa? (a) Ogun (b) Osun (d) Ekiti
20. Ba wo ni a se n polowo eran tutu? (a) E reran e sebe (b) Yee, Obe! (d) ooyo oko
21. Kini a n polowo bayi? Langbe jinna o (a) ewa (b) adalu (d) agbado
22. Nibo ni a kii ti polowo oja ni ode oni ninu wonyi? (a) inu iwe iroyin (b) ori ero alatagba kari aye (d) oju ofurufu
23. Leta gbefe fi aye gba ikini ati aroye (a) Beeni (b) Beeko
24. Adireesi meji ni o maa n wa ninu leta gbefe (a) Beeni (b) Beeko
25. Leta ti ko fi aye gba ikini ati aroye ni _____ (a) leta si ore re ni ilu Eko (b) leta aigbagbefe (d) leta gbefe
26. “O maa to ojo meta” maa n jeyo ninu leta gege bi _____ (a) akole (b) ikadii (d) ikini
27. Leta gbefe kii ni _____ (a) oruko akoleta (b) adiresi agbaleta (d) deeti
28. Ojo ijosin Pataki fun awon Musulumi ni _____ (a) ojo aje (b) ojoru (d) ojo eti
29. Ara ise iyaale ni _____ (a) ija jija (b) ina dida (d) ejo riro
30. Sare! Je apeere gbolohun _____ (a) gbolohun ase (b) gbolohun abuda (d) gbolohun onibo
APA KEJI
1. Se akosile ranpe lori esin Musulumi
2. Daruko ere idaraya merin pelu apeere kookan
3. Daruko oye oba ilu wonyi
(a) Oyo
(b) Ikole – Ekiti
(d) Abeokuta
(e) Ilesa
(e) Idanre
4. Ko bi a ti n polowo awon oja wonyi
(a) agbado sise
(b) Iyan
(d) Eran tutu
(e) Eweedu
(e) Gaari